Isaiah 3

dígí wọn, aṣọ funfun nigínnigín ìbòrí àti ìbòjú.

Isaiah 3:23 (UKJV) The glasses, and the fine linen, and the hoods, and the vails.

21òrùka ọwọ́ àti ti imú,

22àwọn àtàtà aṣọ, àwọ̀lékè, agbádá àti àpamọ́wọ́,

23dígí wọn, aṣọ funfun nigínnigín ìbòrí àti ìbòjú.

24Dípò òórùn dídùn, òórùn búburú ni yóò wá, okùn ni yóò wà dípò àmùrè, orí pípá ni yóò dípò irun ti a ṣe ní ọ̀ṣọ́ aṣọ ọ̀fọ̀ ni yóò dípò aṣọ ẹ̀yẹ ìjóná dípò ẹwà.

25Àwọn ọkùnrin rẹ yóò ti ipa idà ṣubú, àti àwọn jagunjagun rẹ̀ lójú ogun.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.