11Joiada ni baba Jonatani, Jonatani sì ni baba Jaddua.
12Ní ìgbé ayé Joiakimu, wọ̀nyí ni àwọn olórí àwọn ìdílé àwọn àlùfáà: ti ìdílé Seraiah, Meraiah; ti ìdílé Jeremiah, Hananiah;
13ti ìdílé Esra, Meṣullamu; ti ìdílé Amariah, Jehohanani;
14ti ìdílé Malluki, Jonatani; ti ìdílé Ṣekaniah, Josẹfu;
15ti ìdílé Harimu, Adna; ti ìdílé Meraioti Helikai;