33Ó sọ odò di aginjù, àti orísun omi di ilẹ̀ gbígbẹ.
34Ilẹ̀ eléso di aṣálẹ̀ nítorí ìwà búburú àwọn tí ó wà nínú rẹ̀.
35O sọ aginjù di adágún omi àti ilẹ̀ gbígbẹ di orísun omi,
36níbẹ̀ ó mú ẹni tí ebi ń pa wà, wọ́n sì pilẹ̀ ibi tí wọn ó máa gbé.
37Wọn fún irúgbìn, wọ́n sì gbin ọgbà àjàrà tí yóò máa so èso tí ó dára;