Rutu 4

Amminadabu ni baba Nahiṣoni, Nahiṣoni ni baba Salmoni,

Ruth 4:20 (UKJV) And Amminadab brings forth Nahshon, and Nahshon brings forth Salmon,

18Èyí ni ìran Peresi: Peresi ni baba Hesroni,

19Hesroni ni baba Ramu, Ramu ni baba Amminadabu

20Amminadabu ni baba Nahiṣoni, Nahiṣoni ni baba Salmoni,

21Salmoni ni baba Boasi, Boasi ni baba Obedi,

22Obedi ní baba Jese, Jese ni baba Dafidi.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.