Saamu 119

Òfin rẹ jẹ́ òtítọ́ láé; fún mi ní òye kí èmi lè yè.

Psalm 119:144 (UKJV) The righteousness of your testimonies is everlasting: give me understanding, and I shall live.

142Òdodo rẹ wà títí láé òtítọ́ ni òfin rẹ̀.

143Ìyọnu àti ìpọ́njú wá sórí mi, ṣùgbọ́n àṣẹ rẹ ni inú dídùn mi.

144Òfin rẹ jẹ́ òtítọ́ láé; fún mi ní òye kí èmi lè yè.

145Èmi kígbe pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi: dá mi lóhùn Olúwa, èmi yóò sì gbọ́rọ̀ sí àṣẹ rẹ.

146Èmi kígbe pè ọ́; gbà mí èmi yóò sì pa òfin rẹ mọ́.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.